6:1-4Ezekiel 6:1-4
[1]Ọ̀RỌ Oluwa si tọ̀ mi wá, wipe,
[2]Ọmọ enia, kọju rẹ si awọn oke-nla Israeli, si sọtẹlẹ si wọn.
[3]Si wipe, Ẹnyin oke-nla Israeli, ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa Ọlọrun; bayi li Oluwa Ọlọrun wi si awọn oke-nla, si awọn oke kekeke, si awọn odò siṣàn, ati si awọn afonifoji; kiyesi i, Emi, ani Emi, o mu idà wá sori nyin, emi o si pa ibi giga run.
[4]Pẹpẹ nyin yio si di ahoro, ere nyin yio si fọ; okay nyin li emi o si gbe ju siwaju orisa nyin.
Adura: bi o ba ni igbagbo la enu re loni kio si so asotele si ogun abi isoro re loni wa si ri iyipada rere
Amen🫵